Erongba ise Aye daade yii ni lati te si iwaju ninu ogbon atinuda. Ati lati je alabapin igbe aye Alafia, ife fun agbegbe tabi ayika, ife fun asa ijoba tiwa-n-tiwa ati bee bee lo
Bawo ni ase lo kopa
Aye daade da lori atinuda lati gba awon eniyan ni iyanju lati so owo po pelu eto yii.
Orisirisii ona ni a le gba lati kopa ninu eto yi le wa si imuse.
Esi ibi yi fun afikun.
Ilana ati igbese fun imugbooro ati itan kale eto Aye daade
Ero Ayedaade ni lati je ki imuduro wa fun itankale Aye daade kari aye. Lati le je ki awon eniyan mo iwa to to lawijo. Ki won ki o le ma gbe ni irepo pelu liana ti Aye daade fi lele.