Aye Daade

AYE DAADE

Aye daade ni Naijiria

ITAN KEKERE LORI ISAKOSO ILE

Isakoso ile  je apejopo awon enia nipa agbaye  riromo ati fi owo sowopo, lati le se ofin to duro lori, pipe ati alafia ni asiko ti awa yi. O tiraka lati fi han oniruru ona ati awon nkan to dojuko eda ni asiko ti awa ninu re yi. Ona ti won gba nipe ki afi enu sokan nipa iwa onikaluku,akojopo, ile ise,  ijoba ati orisirisii ile eko lati lemo bi won tin se si. (Earth Charter Preamble) Isakoso ile  ti waye lati bi odun mewa seyin,agbaye, pelu asepo awon enia lati 1990s.  Ona won yi ti anse ni gbangba pelu afiowosowopo ni kiko iwe ilana, ohun to je ki Isakoso ile  ni agbekele to daju.      

I. BI ASE DA ISAKOSO ILE SILE

Ninu awon iyanju  OUR COMMON FUTURE (1987), irohin lati World Commission on Environment and Development (WCED), ni o se atokun fun ”Universal Declaration on Environmental Protection and Sustainable Development, ti owa ni Isakoso  titun ti o dari awon orilede lati wo idagbasoke tio dagara. Eyi to je ki Maurice F. Strong, akowe agba ti 1992 Rio Earth Summit (UN Conference on Environment and Development, damoran ni 1990 lati gba Isakoso ile . A pejopo awon ijoba jiroro lori Isakoso ile  ni ibere Rio Earth Summit, sugbon awon ijoba  won  o fowo si ijiroro na rara. The Rio Declaration ti won jumo fowo si ni apejo po na, wa ni orisirisii ona ati asa, sugbon oku die ka to ninu ijiroro ti awon fe ri ninu Isakoso ile.

Ni 1994, Maurice Strong ti oje alaga Earth Council darapo pelu Mikhail Gorbachev gegebi Are Green Cross International lati da Ibere Isakoso ile. Jim McNeill, akowe agba ti WCED ati Queen Beatrice pelu Are  Ruun Lubbers ti Netherlands ni won mu Strong ati Gorbachev papo. Ijoba Dutch ni won faramo eto yi pelu owo ti won gbe kale. Ero okan won ni ki won gbe eto yi kale fun gbogbo enia ati lati ko eto ti onikuluku yio tele ni arin gbogbo enia, ti o yanju fun ojo ola.

Ambassador Mohammed Sahnoun ti Algeria je executive director kini ti Isakoso ile  in 1995 ti o je igbimo agbaye  ti  nse iwadi lori  ayika, idagbasoke ati ofin agbaye wa  ti a mba lo.Isakoso ile  ni office ni Earth Council ni Costa Rica ni abe akoso director agba ti Earth Council, Maximo Kalaw ti Philippines. Ni 1996, Mirian Vilela ti ilu Brazil je Alakoso ile  ni Earth Council. Won da Earth Charter Commission sile ni 1996 fun kiko eto na. Awon alaga meji- Strong ati Gorbachev pelu awon enia Pataki metalelogun  ti won mu kaakiri orilede aiye. Won pe Steven C.Rockfeller, professor esin lati United States lati je alaga fun kiko eto ni January,1997 larin odun meta.

Opolopo oniruru ile ise ati enia kokan ni won nipa ninu idasile Isakoso ile . Marunleogoji Isakoso ile  igbinmo ni adasile. Ijiroro nipa Isakoso ile kakiri agbaye ati lori internet ati ipejopo igbimo ti won se ni Asia, Africa, Central and South America, North America ati Europe. Ijiroro lori Isakoso ile  waye larin awon ojogbon ni agbaye. Eyi tun kun awon lori esin kakakiri aye ati awon ojogbon ni asa ati imo ti science. Isakoso ile waye lati inu United Declaration of Human Rights ti gbogbo awon enia gbe, pelu afiowosowopo ni 1990s. Awon igbinmo sise won pelu World Conservation Union(IUCN) Convention on Environment Law, won si ye iwe ofin ti oto ogorun meji(200) ti awon enia se. Isakoso ile  duro lori agbaye ayika wa ati idagbasoke ofin. Ohun ti won jiroro le lori pelu ipejopo keje UN Summit ni odun 1990, lori ayika, aimafi ya je awon enia, kiko gbogbo enia, omode, obirin, idagba soke ti ilu. Oje ki awon enia mo riri asepo ati ijoba alafia ati idabo fun ayika.

Ohun idaniloju lori Isakoso ile, ti won fi owo si ni ipejopo Earth Charter Commission ni ile ise ti o ga ju ti UNESCO ni Paris ni osu keta odun ti 2000, ni won fenuba merindinlogun imoran, pelu ogotalekan ona imoran, ki won to wa pari eto na pelu ona abayo. Idaniloju pe idile kan, adugbo kan ati aseyori fun gbogbo wa. Nitorina Isakoso ile  fe ki gbogbo enia mo ohun ti onikaluku ye ko se, ki gbogbo wa le gbe papo ati iran tin mbo ni ojo iwaju. O daniloju pe a mo aayika wa pelu eto oro aje, ati eto asa wa ti ole yo sile, sugbon Isakoso ile  ti ko gbogbo re mora. Eto yi ti pin si ona merin lati fi mo ero na:  I   Fifi owo fun ati itoju igbe aye wa;  II   Otito ni ninu ohun ti a da;  III   Idaniloju nipa eto oro aje;  ati  IV   Eto alagbada, lai si edeiyede ati alafia. Isakoso ile  ro pe ti a ba fi esin kan ohun ti yio mu ilosiwaju ba alafia ati inu didun fun ase yori.

II.  IBERE ISAKOSO ILE 2000-2005

Apa keji  Isakoso ile bere pelu ifilole  ni Peace Palace ni The Hague ni osu kefa odun 2000. Lehin eyi,Earth Charter Commission fi riri owo fun Ibere Isakole ile lowo Steering Committee, opolopo awon ti won sise yi wa ninu Earth Charter Commission. Eto nipa ati fun Isakoso ile ni imoran wa lodo Commission ati pe onikaluku lo n fun Isakoso  ile ni imoran won. Ni odun 2000, Mirian Vilela  je director ni Earth Charter Secretariat  to wa ni Unifasiti ti alafia. Fun odun marun ni Isakoso ile  wa ni ogoji ede (40) ati won fi owo si ogorun meji ole ogorun marun awon oniruru ajijose ise, ti millionu  opo enia ni ife si. Lara awon ti ofi owo si Isakoso ile ni UNESCO, World Conservation Union (IUCN), International Council of Local Environmental Initiatives (ICIEI), pelu US Conference of Mayors. Isakoso ile  wa fun idagba soke to yanju pelu alafia ati pe jojo, Isakoso ile  yio je ohun amu ko awon omo ilewe ta alakobere, ile iwe giga ati ile iwe agba to ga ju lo ati iaru be lo.

Of Local Environmental Initiative Earth Charter Fun wa ni ore-ofe ati anfaani lati mo awon ilana ti a le tele ti idagbasoke ati alafia agbaiye yoo fi wa laipe, won bere si ni lo fun eko ni awon ile-iwe sekondiri. Koleji, ile-iwe giga Unifasiti ati ni ile-eko miran ti ki I se ti Oyinbo.

Ni Odun 2002, ni ipade ti a pe akole re ni World Summit on Sustainable Development ti a se ni ilu Johannesburg, won se akitiyan lati ri i pe Earth Charter ri I itewogba. Ni akoko ipade yii, awon are Orile-ede ati opolopo awon adari ile-ise ijoda eni NGO ni o fi owo si eto yii. Iwe ase ti a ko ni ipade ti Johannesburg ko ko awon okoyawo lori eto naa. Sibe, o se atenumo nkan ti Earth Charter duro fun bayii. “A gba pe gege bi iran eniyan, a ni lati ran ara wa lowo, awon nkan ti o wa ni ayika wa, ati awon omo wa.

Akitiyan lati ri itewogba lodo Apapo Orile-ede ti o fi imo sokan United Nations si tun n’ lo lowo.

Ni  Odun 2005, opolopo eniyan ati Orile-ede  ni o ti gbo nipa Earth Charter gege bi liana ati ohun elo fun isora eni dokan  ati idagbasoke.  A n lo gege bi ohun elo fun Alafia laarin awon Orile-ede ti o si n, fun ni ni oye ibi a se n’ dari awon eniyan fun idagbasoke ni agbegbe wa.  O tun je nkan Pataki ti o je ki United Nations ati ECI je  alabapin pelu UNESCO lori eto  Eko fun idagba soke ayika wa ti won n’ ti sise le lori  fun ojo ti o tip e.

Bakan naa, ni Odun 2005, Igbimo ti o n’ mo julo gbogbo eto Earth Charter se awon ayewo Pataki lori eto liana ati ase egbe naa won gbe  egbe naa kari iwon lati mo ibi ti won ku si.  Alan  Atkisson je Okan lara awon ti o gba Igbimo ni iyanju ni akoko ayewo naa.  Igbelewon  yii  se koko, o si se Okunfa ipade ti o ko ogorun merin awon adari ti o n’ sise ni eka idagbasoke ati ayika  JO.  Nibi ipade yii ni ati yan Alan Atkisson ni Oludari Earth Charter.

Ni akoko ipade ti won se ni Netherlands awon ile-ise kan ti a n’ pe ni KIT ni Amsterdam te iwe kan jade te  iwe kan jade ti Peter Blaze, Corcoran, Mirian Vileta ati Alide Roerink se Olootu iwe naa ti akole re n’je The Earth Charter in Action: Towards A Sustainable World.  Iwe yii ni Ogota aroko ti awon Olori ati Olufowosi ko lori itesiwaju ati itoju ayika wa ati eto Earth Charter.

Ifilole isakoso lori ile (ti a n’ pe ni Earth Charter 2006 – di akoko yii

Ni Odun 2006, a se atunto ile-ise Earth Charter, a sib ere si nip e ni ECI.

Earth Charter International:  A tun yan awon omo Igbimo metalelogun ti yoo ma se alakoso egbe naa.  Steven  Rockefeller, Razeena Waggiet ti ilu Indonesia ni a yan gege bi awon alaga titun fun Igbimo naa.  Won si ofisi kan Stocholm, Sweden, fun awon eniyan lati  ma fi irohin ati awon nkan miiran ranse sibe  Olu ile-ise nola Earth Charter ti o wa ni University For Peace ni a so di eka miiran  fun egbe naa.  Igbimo yii si bere eto titun ti  yoo mu ilosiwaju wa fun igba keta.

Awon Ijoba Orile-ede kaakiri gbogbo aye si ni fi ife han si eto Earth Charter.  Ijoba ile Brazil jo ni adehun pelu Earth Charter, lati ma se  itoju ayika ati agbegbe Brazil, eto ti Leonardo Boff ati Miranda da sile ni Petropolis lati je ki gbogbo Omo Brazil mo nipa eto yii.  Nigba ajodun “itoju ile aye Earth Day ni ilu Mexico ni Odun 2007.  Ijoba ilu Mexico se ileri lati maa Earth Charter gege ohun elo ni ile-iwe won. Bakan naa ni awon ilu miiran naa, se ileri lati gba awon liana ti o wa nninu ofin Earth Charter die, ninu won, Queensland, Australia, Tatarstan ni ilu Russia, ati awon ilu bii Calgary (Canada)  Munich (Germany) New Dehli, Oslo (Norway) ati Sao Paulo (Brazil).

Ni Odun 2006 ati 2007, Iye awon ti o fowo si Eto Earth Charter di Egberun merin ati Ogorun mefa egbe ototo ni o fi owo si eto yii, ti Earth Charter sib ere si ni gba awon alejo lorisiirisii to n’ lo bi egberun lona Ogorun eniyan lori ero ayara bi asa Website laarin Osu kan.  Won da eto tuntun sile fun awon Onisowo ati ni eka esin.  Eto ti awon odo naa bere si ni gboro si ti won si ni eka won ni Orile-ede metalelogun ti awon Onifowosowopo pelu Earth Charter si je metadinlogun ni awon Orile-ede Mejidinlogota  Ototo Egbe yii bere si ni dagba o si n’ fun awon Orile-ede ni irohin ati iyato to n’ ba ayik wa lojoojumo Climate Change, ati pe a gbodo pawopo ki a gbe igbese  A pe Earth Charter lati kopa ninu pade ajo-nla lori Alafia Peace ti are apapo awon Orile-ede ti o fi imo sokan UN se alakoso ipade naa.

Lehin Ipade Olojo meta lori bi a se le se eto fun ojo iwaju Long-range Strategic planning eyi ti Oscar Moto mura se alakoso re ni Igbimo Earth Council tun se ifilole eto titun lori bi egbe yii yoo se maa dagba si lore kore.

Lehin Odun meji, ti o ti n’ se alakoso egbe yii Earth Charter, Alan Atkisson sokale gege bi alakoso egbe yii ni ipari Odun 2007 lati  le koju mo awon eto naa.  A yan Mirian Vitela gege bi alakoso egbe yii lekan si, won tun da ofisi egbe naa pada si University For Peace ni ilu Costa Rica.  Bakan naa ni odun 2007, ema Witoelar sokale gege bi okan ninu awon alaga egbe naa, asi yan Brendan Mackey gege bi alaga titun.

Ti  a ba wo ojo iwaju, a o ri I pe 

Ni  Odun 2005, opolopo eniyan ati Orile-ede  ni o ti gbo nipa Earth Charter gege bi liana ati ohun elo fun isora eni dokan  ati idagbasoke.  A n lo gege bi ohun elo fun Alafia laarin awon Orile-ede ti o si n, fun ni ni oye ibi a se n’ dari awon eniyan fun idagbasoke ni agbegbe wa.  O tun je nkan Pataki ti o je ki United Nations ati ECI je  alabapin pelu UNESCO lori eto  Eko fun idagba soke ayika wa ti won n’ ti sise le lori  fun ojo ti o tip e.

Bakan naa, ni Odun 2005, Igbimo ti o n’ mo julo gbogbo eto Earth Charter se awon ayewo Pataki lori eto liana ati ase egbe naa won gbe  egbe naa kari iwon lati mo ibi ti won ku si.  Alan  Atkisson je Okan lara awon ti o gba Igbimo ni iyanju ni akoko ayewo naa.  Igbelewon  yii  se koko, o si se Okunfa ipade ti o ko ogorun merin awon adari ti o n’ sise ni eka idagbasoke ati ayika  JO.  Nibi ipade yii ni ati yan Alan Atkisson ni Oludari Earth Charter.

Ni akoko ipade ti won se ni Netherlands awon ile-ise kan ti a n’ pe ni KIT ni Amsterdam te iwe kan jade te  iwe kan jade ti Peter Blaze, Corcoran, Mirian Vileta ati Alide Roerink se Olootu iwe naa ti akole re n’je The Earth Charter in Action: Towards A Sustainable World.  Iwe yii ni Ogota aroko ti awon Olori ati Olufowosi ko lori itesiwaju ati itoju ayika wa ati eto Earth Charter.

III. Ifilole isakoso lori ile (ti a n’ pe ni Earth Charter 2006 – di akoko yii)

Ni Odun 2006, a se atunto ile-ise Earth Charter, a sib ere si nip e ni ECI. Earth Charter International:  A tun yan awon omo Igbimo metalelogun ti yoo ma se alakoso egbe naa.  Steven Rockefeller, Razeena Waggiet ti ilu Indonesia ni a yan gege bi awon alaga titun fun Igbimo naa.  Won si ofisi kan Stocholm, Sweden, fun awon eniyan lati  ma fi irohin ati awon nkan miiran ranse sibe  Olu ile-ise nola Earth Charter ti o wa ni University For Peace ni a so di eka miiran  fun egbe naa.  Igbimo yii si bere eto titun ti  yoo mu ilosiwaju wa fun igba keta.

Awon Ijoba Orile-ede kaakiri gbogbo aye si ni fi ife han si eto Earth Charter.  Ijoba ile Brazil jo ni adehun pelu Earth Charter, lati ma se  itoju ayika ati agbegbe Brazil, eto ti Leonardo Boff ati Miranda da sile ni Petropolis lati je ki gbogbo Omo Brazil mo nipa eto yii.  Nigba ajodun “itoju ile aye Earth Day ni ilu Mexico ni Odun 2007.  Ijoba ilu Mexico se ileri lati maa Earth Charter gege ohun elo ni ile-iwe won. Bakan naa ni awon ilu miiran naa, se ileri lati gba awon liana ti o wa nninu ofin Earth Charter die, ninu won, Queensland, Australia, Tatarstan ni ilu Russia, ati awon ilu bii Calgary (Canada)  Munich (Germany) New Dehli, Oslo (Norway) ati Sao Paulo (Brazil).

Ni Odun 2006 ati 2007, Iye awon ti o fowo si Eto Earth Charter di Egberun merin ati Ogorun mefa egbe ototo ni o fi owo si eto yii, ti Earth Charter sib ere si ni gba awon alejo lorisiirisii to n’ lo bi egberun lona Ogorun eniyan lori ero ayara bi asa Website laarin Osu kan.  Won da eto tuntun sile fun awon Onisowo ati ni eka esin.  Eto ti awon odo naa bere si ni gboro si ti won si ni eka won ni Orile-ede metalelogun ti awon Onifowosowopo pelu Earth Charter si je metadinlogun ni awon Orile-ede Mejidinlogota  Ototo Egbe yii bere si ni dagba o si n’ fun awon Orile-ede ni irohin ati iyato to n’ ba ayika wa lojoojumo Climate Change, ati pe a gbodo pawopo ki a gbe igbese  A pe Earth Charter lati kopa ninu pade ajo-nla lori Alafia Peace ti are apapo awon Orile-ede ti o fi imo sokan UN se alakoso ipade naa.
Lehin Ipade Olojo meta lori bi a se le se eto fun ojo iwaju Long-range Strategic planning eyi ti Oscar Moto mura se alakoso re ni Igbimo Earth Council tun se ifilole eto titun lori bi egbe yii yoo se maa dagba si lore kore.

Lehin Odun meji, ti o ti n’ se alakoso egbe yii Earth Charter, Alan Atkisson sokale gege bi alakoso egbe yii ni ipari Odun 2007 lati  le koju mo awon eto naa.  A yan Mirian Vitela gege bi alakoso egbe yii lekan si, won tun da ofisi egbe naa pada si University For Peace ni ilu Costa Rica.  Bakan naa ni odun 2007, ema Witoelar sokale gege bi okan ninu awon alaga egbe naa, asi yan Brendan Mackey gege bi alaga titun.

Lati  mu alafia, ati lati gbe ara won ka ori iwon, ki won le mo boya awon pe oju osu won tabi bee ko.  Ninu ipade (ECI) ti won se ni osun Ebibi 2008, won gba pe won o se eto ti yoo mojuto ojo iwaju, nipa eyi, won da igbimo(komiti) mefa ototo sile ti yoo se eto titun ti yoo si se atilehin fun awon onisowo, Eko, awon oniroyin, eto Esin, (UN) ati awon odo.