Aye Daade

AYE DAADE

Aye daade ni Naijiria

 
 
(Earth Charter Iniciative timeline) Awon akoko ti o se Pataki ninu idasile (ECI)
1987 Akojopo awon Orile-ede ti o n’sise lori itoju ayika wa ati idagbasoke (Brundt land commission) damoran pe ki a da egbe kan tabi eka kan sile ti yoo maa mojuto eto idagbasoke.
1992 Ipade awon to n’ se iwadi lori ile Earth Summit ti won se ni Rio de Janiero, ni ati ko awon ofin ati ilana, ati ete egbe yii ti yoo majuto eto ile ni gbogbo igba sugbon ijoba se igbimo kan ti a n’pe ni Rio Declaration on Environment and Development. Ni abe akoso Maurice Strong, akowe agba RIO Earth Summit a da awon alakoso kan sile lati mojuto eto bi gbogbo awon eniyan Orile-aye o se pade lati dijo soro ninu re ati lati je ki awon eniyan mo pataki lati da eka kan sile ti yoo si maa mojuto idagbasoke.
1994 Alaga Igbimo to n’ mojuto ile Earth Council Maurice Strong ati Mikhail Gorbachex, are Green Cross International se idasile eka ti yoo ko ofin ilana  ati nkan ti isakoso lori ile Earth Charter duro fun. Ijoba ile Dutch se iranlowo pelu owo.
1995 Awon Eka mejeeji yii: Earth Council ati Green Council bere si ni ba awon Orile-ede soro nipa bi won o se da egbe yii sile ti yoo mojuto isoro ati idagbasoke awon eniyan. Eyi ni o se okunfa ipade kan ti won se ti akole re n’je: The Hague Earth Charter Workshop ti a si yan ile-ise ibi ti awon alakoso yii ti n’ pade ni ojulowo ile-ise isokoso fun ile Earth Charter.
1996 Ni odun yii ni awon alakoso bere si ni palemo fun ipade. Ni ipari odun, eka ti a n’ pe ni Green Cross International ati Earth Council se idasile igbimo ti yoo ko ofin jade.
1997 Ile-ise isakoso fun ile Earth Charter Commission pade fun ipade won akoko ti RIO + 5 ni ilu RIO de jeneiro A fi ise to n’lo lowo lori iwe asehan. Ni ipari ijiroro yii, a gba awon alakoso ni iyanju lati tunbo ma ba awon orile-ede soro nipa eto naa.
1998 Opolopo awon egbe lorisiirisii darapo mo egbe isakoso lori ile Earth Charter ti won si di omo igbimo orile-ede National Committee ni Orile-ede otooto ti o lo bi arundun logoji 35 Countries. Awon eka ati egbe yii gbimo po, won si gba lati maa lo ofin yii.
1999 Apa keji ofin yii jade ni osu igbe April ti won tesiwaju lati tunbo ma a ba awon orile-ede miran soro lori eto naa. Awon omo Igbimo Orile-ede po si di aarundinlaadota 45.
2000 Ninu osu Erena March ile-ise isakoso lori ile Earth Charter Commission pade ni ilu Paris, France lati fowo si iwe ase egbe yii. A si se ifilole re ninu osu okudu June ni peace palace Hague. Won yan awon omo igbimo ti yoo ma se akoso ti yoo eto yii. Nkan ti a se koko ti won si fe ki won mojuto ni eto yi yoo se di mimo ti yo si ni ifowo si gbogbo ara ilu awon onisowo, ati ijoba, ti a o si ma lo iwe ase yii, ni awon ile-iwe giga Universities ati awon ibo miiran.
2002 Egbe yii gbiyanju lati rii pe opolopo orile-ede fi owo si eto yii nibi ipade agbaye lori idagbasoke ti a se ni ilu Johannesburg. Nibi ipade yii opolopo awon Orile-ede ati awon eka  ti ki I se ti ijoba.
NGOs ni o fi ife han si eto yii. Sugbon apapo lgbimo Orile-ede ti imo won sokan United Nations ko ti fi owo si iwe  egbe yii.
2005 Ni akoko yii ati ko eto ati ilana egbe yii lade ni orisii ede bi i mejilelogbon (32 languages) kaakiri gbogbo agbaiye, ti awon orisii egbe bi egberun meji ati ogorun merin 2,400 fowo si pelu UNESCO, IUCN ati ICLEI. Gbogbo nkan ti o n’ sele lati odun 2000 – 2005 ninu egbe yii ni won se agbeyewo won. Ninu osu Belu (November) odun naa ni ipade Earth Charter +5 waye ni ilu Amsterdam. Nibi ipade yii ni won ti pari eto Olodun marun-un ti won dawole, ti won si ni lati gbe egbe yi lo si waju.
2006 Titun Earth Charter International Council pelu metalelogun (23) enia ni won gba ise lowo Igbimo Committee to mojuto eto ati awon osise secretariat, ni won wape ara won ni Earth Charter International (ECI). 
2008 Won yan eniyan metalelogun miiran jakejado agbaiye lati ma se alakoso egbe yii ati ko ilana ofin ati eto egbe yii si orisii ogoji (40) ede, ti o si ri itewogba ati ifowosi ati ogorun mefa egbe otooto ti o n’se asoju oke aimoye awon eniyan. Igbimo yii ti gba lati ri’I pe a pin eto yii si orisii eka mefa ototo ti yoo lee da duro. Awon eka naa ni; eto owo sise, eto eko, eto iroyin, eto esin, apapo orile-ede to gbimo po United Nations ati awon odo.

A short Itan of the Earth Charter Initiative...