Ifaara.
(ECI) gba gbogbo eniyan ni iyanju lati kopa ninu ete Earth Charter . A nilo ifowosopo ati atilehin re. Nitori eyi, (ECI) ti n se eto ti yoo mu idagbasoke ba egbe yii jakejado agbaiye, ti yoo si mu, idagbasoke baa awon eniyan, Ilu wa, ati egbe ti a ba wa.
Bi ECI ti fe se eto yii, yoo tesiwaju lati je ki Earth Charter je ilumomika kaakiri agbaiye nipa opolopo ise ti won yoo dawole. Eto tuntun yii se Pataki nitori pe ile-ise Earth Charter ko le dari opolopo eto lokansoso, bikose pe ki won sise akoso awon eto die kan ti yoo mu idagbasoke ba Egbe naa.
Awon ilana ti a ko si isale yii wa lati ran awon eniyan lowo, ati lati to won si ona lori awon eto ti yoo mu idagbasoke ba Ilu wa, pelu ibamu pelu ete, iran ati ilana Earth Charter.
Idi Pataki ti a tun fun nilo ilana ati ofin yii ni pe yoo fun wa ni anfaani ati ri daaju pe a tele ilana ati ofin lati mu egbe yii dagba. E je ka ri awon ilana naa gege bii nkan ti yoo je ki opolopo awon eniyan kopa ninu eto yii kaakiri gbogbo aye.
A ko ilana yii fun awon eniyan nii, botile je pe ijoba, awon ile-ise nla, ati awon egbe ni ipa Pataki ti won gbodo ko sibe awa gan funra wa gbodo ji giri si awon ilana yii ki a si ko ipa ti o ba ye fun idabasoke Ilu wa.
Ofin ati ilana yii ki I se baraku ti a o nile se atunse rara. (ECI) yoo maa se ayewo ati atunse lori ilana lati igba de igba ki o ba le ba akako ati igba mu, ki o si ri itewogba jakejado agbaiye. E le fi akiyesi ati imoran yin ranse si wa nigbakugba.
OFIN ATI ILANA NAA
- Bere pelu Earth Charter . Je ki ofin ati ilana Earth Charter je nkan ti oo tele ti o ba fe kopa ninu iran ati ise egbe yii.
- Je apeere rere Gbiyanju lati ri I pe o je apeere rere fun Earth Charter ni ile ibi ise ati ni adugbo re.
- Fi se gbogbo nkan pelu igboya, ki o si ni igbagbo pe oo le mu iyipada wa, nipa eyi, iwo naa yoo le ran iyanju awon elomiran lowo.
- Fowosowopo pelu awon elomiran lati mu iyato ti o peye wa. Gbiyanju lati wa idahun si isoro won.
- Ro awon elomiran ni agbara. Ri i pe o se atilehin fun awon eniyan miiran nipa fifun won ni oore-ofe kan pelu ogbon inu won.
- Se agbateru ibowo fun ara eni, ati igbora eniyo. Gbiyanju lati ri i pe ajosopo re pelu awon eniyan miiran, asa miiran ati Ilu miiran dara daa daa. Ti ikusinu ba wa, ri i pe e jo ni ajosopo ti yoo mu alafia wa.
- Ko awon eniyan lati le da duro. Pologo Earth Charter fun awon eniyan, lehin eyi, ko won lati le da duro, mase gbiyanju ati ma dari won. Je ki won ko ara won jo, ki won si se nkan ti yoo mu itesiwaju wa.
- Dojuko nkan ti o fa isoro fi ero okan re dojuko gbogbo nkan ti o ba n fa ifa seyin to n dojuko iran eniyan, mase je ki isoro naa tabi ifaseyin naa domi tutu si o lokan.
- Fi ara re jin, sugbon je ko rorun fun o lati se atuse. Je eni ti o fi ara re jin, ti o si n tele ilana Earth Charter lati fi mu ilosiwaju wa, sugbon je ki o rorun fun o lati se atunse nibi ti o ba ti ye, bi igba ti n yi pada.
- Ero re ko gbodo dale owo nikan. Je eni ti o n ro ori re daa. Ero re ko gbodo da lori opo nikan, nigba miiran, o gbodo lo okan ati ogbon ori re.
- Lo awon ero igbalode pelu ogbon. Opolopo awon eniyan ko mo bi a se n lo awon ero igbalode yii. Nitori naa, ti a ba fe lo awon ero ati nkan igbalode yii, e je ki a lo eyi ti ko ni da awon eniyan lamu.
- Dabobo iyi ilana yii: Igbakugba ti a ba n’ soro, so itumo, tabi se agbekale awon ilana Earth Charter, e je ki a je olotito si oro inu ilana yii, ki a si ri i pe awon ti o mo iyi egbe yii nikan ni a polongo egbe yii fun.